Àwọn Ọba Keji 6:23 BM

23 Nítorí náà, ọba Israẹli pèsè oúnjẹ fún wọn lọpọlọpọ. Lẹ́yìn tí wọ́n ti jẹ, tí wọ́n sì ti mu, wọ́n pada sọ́dọ̀ oluwa wọn. Láti ọjọ́ náà ni àwọn ọmọ ogun Siria kò ti gbógun ti ilẹ̀ Israẹli mọ́.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 6

Wo Àwọn Ọba Keji 6:23 ni o tọ