Àwọn Ọba Keji 6:8 BM

8 Ní ìgbà kan tí ọba Siria ń bá ọba Israẹli jagun, ó bá àwọn olórí ogun rẹ̀ gbèrò ibi tí wọn yóo ba sí de àwọn ọmọ ogun Israẹli.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 6

Wo Àwọn Ọba Keji 6:8 ni o tọ