Àwọn Ọba Keji 7:15 BM

15 Àwọn ọkunrin náà lọ títí dé odò Jọdani. Ní gbogbo ojú ọ̀nà náà ni wọ́n ti ń rí àwọn aṣọ ati àwọn ohun ìjà tí àwọn ará Siria jù sọnù nígbà tí wọn ń sá lọ. Wọ́n sì pada wá ròyìn fún ọba.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 7

Wo Àwọn Ọba Keji 7:15 ni o tọ