Àwọn Ọba Keji 7:17 BM

17 Ọba Israẹli fi ìtọ́jú ẹnubodè ìlú sí abẹ́ àkóso ọ̀gágun tí ó jẹ́ aṣojú rẹ̀. Àwọn eniyan sì tẹ ọ̀gágun náà pa, gẹ́gẹ́ bí Eliṣa ti sọtẹ́lẹ̀ nígbà tí ọba lọ sọ́dọ̀ rẹ̀.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 7

Wo Àwọn Ọba Keji 7:17 ni o tọ