Àwọn Ọba Keji 7:5 BM

5 Nígbà tí ọjọ́ bẹ̀rẹ̀ sí pofírí, wọ́n lọ sí ibùdó ogun àwọn ará Siria, nígbà tí wọ́n dé ibẹ̀, wọn kò rí ẹnìkan kan.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 7

Wo Àwọn Ọba Keji 7:5 ni o tọ