Àwọn Ọba Keji 7:7 BM

7 Nítorí náà, wọ́n sá lọ ní àṣáálẹ́ ọjọ́ náà, wọ́n fi ibùdó ogun wọn ati àwọn ẹṣin wọn ati àwọn kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ wọn sílẹ̀, wọ́n sì sá àsálà fún ẹ̀mí wọn.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 7

Wo Àwọn Ọba Keji 7:7 ni o tọ