Àwọn Ọba Keji 8:24 BM

24 Jehoramu kú, wọ́n sì sin ín sí ibojì àwọn ọba ní ìlú Dafidi. Ahasaya ọmọ rẹ̀ sì jọba lẹ́yìn rẹ̀.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 8

Wo Àwọn Ọba Keji 8:24 ni o tọ