Àwọn Ọba Keji 8:26 BM

26 Ẹni ọdún mejilelogun ni nígbà tí ó jọba ni Jerusalẹmu, ó sì jọba fún ọdún kan. Atalaya ni ìyá rẹ̀, ọmọ Omiri, ọba ilẹ̀ Israẹli.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 8

Wo Àwọn Ọba Keji 8:26 ni o tọ