Àwọn Ọba Keji 8:8 BM

8 ọba sọ fún Hasaeli, ọ̀kan ninu àwọn iranṣẹ rẹ̀ pé, “Mú ẹ̀bùn lọ́wọ́, kí o sì lọ bá wolii náà, kí o sọ fún un pé kí ó bá mi bèèrè lọ́wọ́ OLUWA bóyá n óo yè ninu àìsàn yìí.”

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 8

Wo Àwọn Ọba Keji 8:8 ni o tọ