Àwọn Ọba Keji 9:13 BM

13 Lẹ́sẹ̀ kan náà, àwọn ẹgbẹ́ rẹ̀ tẹ́ aṣọ wọn sílẹ̀ fún un kí ó dúró lé, wọ́n sì fun fèrè pé, “Kabiyesi, Jehu ọba!”

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 9

Wo Àwọn Ọba Keji 9:13 ni o tọ