Àwọn Ọba Keji 9:19 BM

19 Wọ́n bá tún rán oníṣẹ́ mìíràn lọ láti bèèrè ìbéèrè kan náà lọ́wọ́ Jehu. Ó tún dáhùn pé “Kí ni o fẹ́ fi alaafia ṣe? Bọ́ sẹ́yìn mi.”

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 9

Wo Àwọn Ọba Keji 9:19 ni o tọ