Àwọn Ọba Keji 9:32 BM

32 Jehu bá gbé ojú rẹ̀ sókè, ó ní, “Ta ló wà lẹ́yìn mi ninu yín?” Àwọn ìwẹ̀fà meji tabi mẹta sì yọjú sí i láti ojú fèrèsé.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 9

Wo Àwọn Ọba Keji 9:32 ni o tọ