Àwọn Ọba Keji 9:34 BM

34 Lẹ́yìn náà, ó wọlé, ó jẹ, ó mu, lẹ́yìn náà, ó ní, “Ẹ lọ sin òkú obinrin ẹni ègún yìí nítorí pé ọmọ ọba ni.”

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 9

Wo Àwọn Ọba Keji 9:34 ni o tọ