Àwọn Ọba Keji 9:5 BM

5 Nígbà tí ó dé ibẹ̀, ó bá àwọn olórí ogun níbi tí wọ́n ti ń ṣe ìpàdé. Ó wí pé, “Balogun, wọ́n rán mi níṣẹ́ sí ọ.”Jehu bá bèèrè pé, “Ta ni ninu wa?”Ọdọmọkunrin náà bá dáhùn pé, “Ìwọ ni, Balogun.”

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 9

Wo Àwọn Ọba Keji 9:5 ni o tọ