Nehemaya 12:23 BM

23 Àkọsílẹ̀ orúkọ àwọn baálé baálé ninu àwọn ọmọ Lefi títí di ìgbà ayé Johanani ọmọ Eliaṣibu wà ninu ìwé Kronika.

Ka pipe ipin Nehemaya 12

Wo Nehemaya 12:23 ni o tọ