Nehemaya 12:29 BM

29 bákan náà ni láti Betigiligali ati láti ẹkùn Geba, ati Asimafeti, nítorí pé àwọn akọrin kọ́ ìletò fún ara wọn ní agbègbè Jerusalẹmu.

Ka pipe ipin Nehemaya 12

Wo Nehemaya 12:29 ni o tọ