Nehemaya 12:8 BM

8 Àwọn ọmọ Lefi ni: Jeṣua, Binui ati Kadimieli; Ṣerebaya, Juda, ati Matanaya, tí òun pẹlu àwọn arakunrin rẹ̀ wà nídìí ètò àwọn orin ọpẹ́.

Ka pipe ipin Nehemaya 12

Wo Nehemaya 12:8 ni o tọ