11 Nítorí náà, mo bá àwọn olórí wí, mo ní “Kí ló dé tí ilé Ọlọrun fi di àpatì?” Mo kó wọn jọ, mo sì dá wọn pada sí ààyè wọn.
Ka pipe ipin Nehemaya 13
Wo Nehemaya 13:11 ni o tọ