Nehemaya 13:14 BM

14 Ọlọrun mi, ranti mi, nítorí nǹkan wọnyi, kí o má sì pa gbogbo nǹkan rere tí mo ti ṣe sí tẹmpili rẹ rẹ́ ati àwọn iṣẹ́ ìsìn rẹ̀.

Ka pipe ipin Nehemaya 13

Wo Nehemaya 13:14 ni o tọ