Nehemaya 13:20 BM

20 Gbogbo àwọn oníṣòwò ati àwọn tí wọn ń ta oríṣìíríṣìí nǹkan sùn sí ẹ̀yìn odi Jerusalẹmu bíi ẹ̀ẹ̀kan tabi ẹẹmeji.

Ka pipe ipin Nehemaya 13

Wo Nehemaya 13:20 ni o tọ