Nehemaya 13:4 BM

4 Kí ó tó di àkókò náà, Eliaṣibu alufaa, tí wọ́n yàn láti máa ṣe àkóso àwọn yàrá ilé Ọlọrun wa, tí ó sì ní àjọṣe pẹlu Tobaya,

Ka pipe ipin Nehemaya 13

Wo Nehemaya 13:4 ni o tọ