Nehemaya 4:15 BM

15 Nígbà tí àwọn ọ̀tá wa ti gbọ́ pé a ti mọ àṣírí ète wọn, ati pé Ọlọrun ti da ìmọ̀ wọn rú, gbogbo wa pada sí ibi odi náà, olukuluku sì ń ṣe iṣẹ́ tirẹ̀.

Ka pipe ipin Nehemaya 4

Wo Nehemaya 4:15 ni o tọ