Nehemaya 4:22 BM

22 Mo tún sọ fún àwọn eniyan náà pé, “Kí olukuluku ati iranṣẹ rẹ̀ sùn ní Jerusalẹmu, kí wọ́n lè máa ṣọ́ ìlú lálẹ́, kí wọ́n sì máa ṣiṣẹ́ ní ojú ọ̀sán.”

Ka pipe ipin Nehemaya 4

Wo Nehemaya 4:22 ni o tọ