9 Ṣugbọn a gbadura sí Ọlọrun wa, a sì yan àwọn olùṣọ́ láti máa ṣọ́ ibẹ̀ tọ̀sán-tòru.
Ka pipe ipin Nehemaya 4
Wo Nehemaya 4:9 ni o tọ