Nehemaya 5:3 BM

3 Àwọn mìíràn ń sọ pé, “A ti fi ilẹ̀ oko wa yáwó, ati ọgbà àjàrà wa, ati ilé wa, kí á lè rówó ra ọkà nítorí ìyàn tí ó mú yìí.”

Ka pipe ipin Nehemaya 5

Wo Nehemaya 5:3 ni o tọ