Nehemaya 6:4 BM

4 Ìgbà mẹrin ni wọ́n ranṣẹ pè mí bẹ́ẹ̀, èsì kan náà sì ni mo fún wọn ní ìgbà mẹrẹẹrin.

Ka pipe ipin Nehemaya 6

Wo Nehemaya 6:4 ni o tọ