Nehemaya 8:11 BM

11 Àwọn ọmọ Lefi rẹ àwọn eniyan náà lẹ́kún, wọ́n sọ fún wọn pé, “Ẹ dákẹ́, nítorí pé ọjọ́ mímọ́ ni ọjọ́ òní, ẹ má bọkàn jẹ́.”

Ka pipe ipin Nehemaya 8

Wo Nehemaya 8:11 ni o tọ