Nehemaya 9:36 BM

36 Wò ó ẹrú ni wá lónìí lórí ilẹ̀ tí o fún àwọn baba wa pé kí wọ́n máa gbádùn àwọn èso inú rẹ̀ ati àwọn nǹkan dáradára ibẹ̀. Wò ó, a ti di ẹrú lórí ilẹ̀ náà.

Ka pipe ipin Nehemaya 9

Wo Nehemaya 9:36 ni o tọ