16 Háà, o mà dára o! Olùfẹ́ mi,o lẹ́wà gan-an ni.Ewéko tútù ni yóo jẹ́ ibùsùn wa.
Ka pipe ipin Orin Solomoni 1
Wo Orin Solomoni 1:16 ni o tọ