Orin Solomoni 2:15 BM

15 Mú àwọn kọ̀lọ̀kọ̀lọ̀ wọ̀n-ọn-nì,àwọn kọ̀lọ̀kọ̀lọ̀ kéékèèké tí wọn ń ba ọgbà àjàrà jẹ́,nítorí ọgbà àjàrà wa tí ń tanná.

Ka pipe ipin Orin Solomoni 2

Wo Orin Solomoni 2:15 ni o tọ