Orin Solomoni 3:4 BM

4 Mo fẹ́rẹ̀ má tíì kúrò lọ́dọ̀ wọn,ni mo bá rí ẹni tí ọkàn mi fẹ́.Mo dì í mú, n kò sì jẹ́ kí ó lọ,títí tí mo fi mú un dé ilé ìyá mi,ninu ìyẹ̀wù ẹni tí ó lóyún mi.

Ka pipe ipin Orin Solomoni 3

Wo Orin Solomoni 3:4 ni o tọ