Orin Solomoni 3:7 BM

7 Wò ó! Solomoni ni wọ́n ń gbé bọ̀, lórí ìtẹ́ rẹ̀,ọgọta akọni ọkunrin, lára àwọn akọni Israẹli,ni ó yí ìtẹ́ rẹ̀ ká.

Ka pipe ipin Orin Solomoni 3

Wo Orin Solomoni 3:7 ni o tọ