Orin Solomoni 4:14 BM

14 igi nadi ati Safironi, Kalamusi ati Sinamoni,pẹlu oríṣìíríṣìí igi turari,igi òjíá, ati ti aloe,ati àwọn ojúlówó turari tí òórùn wọn dára jùlọ.

Ka pipe ipin Orin Solomoni 4

Wo Orin Solomoni 4:14 ni o tọ