6 Gbé mi lé oókan àyà rẹ bí èdìdì ìfẹ́,bí èdìdì, ní apá rẹ;nítorí ìfẹ́ lágbára bí ikú.Owú jíjẹ burú, àfi bí isà òkú.A máa jó bí iná,bí ọwọ́ iná tí ó lágbára.
Ka pipe ipin Orin Solomoni 8
Wo Orin Solomoni 8:6 ni o tọ