Samuẹli Keji 1:1 BM

1 Lẹ́yìn ikú Saulu, nígbà tí Dafidi pada dé láti ojú ogun, níbi tí ó ti ṣẹgun àwọn ará Amaleki, ó dúró ní ìlú Sikilagi fún ọjọ́ meji.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 1

Wo Samuẹli Keji 1:1 ni o tọ