Samuẹli Keji 1:11 BM

11 Ni Dafidi ati gbogbo àwọn tí wọ́n wà pẹlu rẹ̀ bá fa aṣọ wọn ya láti fi ìbànújẹ́ wọn hàn.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 1

Wo Samuẹli Keji 1:11 ni o tọ