Samuẹli Keji 1:15 BM

15 Ni Dafidi bá pàṣẹ pé kí ọ̀kan ninu àwọn ọkunrin tí wọ́n wà lọ́dọ̀ rẹ̀, lọ pa ọdọmọkunrin ará Amaleki náà. Ọkunrin náà bá pa á.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 1

Wo Samuẹli Keji 1:15 ni o tọ