Samuẹli Keji 1:3 BM

3 Dafidi bèèrè lọ́wọ́ rẹ̀ pé, “Níbo ni o ti ń bọ̀?”Ọdọmọkunrin náà dáhùn pé, “Láti inú àgọ́ àwọn ọmọ Israẹli ni mo ti sá àsálà.”

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 1

Wo Samuẹli Keji 1:3 ni o tọ