Samuẹli Keji 11:23 BM

23 Ó ní, “Àwọn ọ̀tá wa lágbára jù wá lọ, wọ́n sì jáde láti inú ìlú wọn láti bá wa jà ninu pápá, ṣugbọn a lé wọn pada títí dé ẹnubodè ìlú wọn.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 11

Wo Samuẹli Keji 11:23 ni o tọ