17 Àwọn àgbààgbà tí wọ́n wà ninu ilé rẹ̀ rọ̀ ọ́, pé kí ó dìde nílẹ̀, ṣugbọn ó kọ̀, kò sì bá wọn jẹ nǹkankan.
Ka pipe ipin Samuẹli Keji 12
Wo Samuẹli Keji 12:17 ni o tọ