Samuẹli Keji 12:24 BM

24 Dafidi bá tu Batiṣeba, aya rẹ̀ ninu, ó bá a lòpọ̀, ó sì bí ọmọkunrin kan fún un. Dafidi sọ ọmọ yìí ní Solomoni. OLUWA fẹ́ràn ọmọ náà,

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 12

Wo Samuẹli Keji 12:24 ni o tọ