Samuẹli Keji 12:26 BM

26 Ní gbogbo àkókò yìí, Joabu wà níbi tí ó ti gbógun ti Raba, olú ìlú àwọn ará Amoni, ó sì gba ìlú ọba wọn.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 12

Wo Samuẹli Keji 12:26 ni o tọ