Samuẹli Keji 12:28 BM

28 kó àwọn ọmọ ogun yòókù jọ, kí o kọlu ìlú náà, kí o sì gbà á fúnra rẹ. N kò fẹ́ gba ìlú náà kí ògo gbígbà rẹ̀ má baà jẹ́ tèmi.”

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 12

Wo Samuẹli Keji 12:28 ni o tọ