Samuẹli Keji 12:5 BM

5 Nígbà tí Dafidi gbọ́ ọ̀rọ̀ yìí, inú bí i gidigidi sí ọkunrin ọlọ́rọ̀ náà tóbẹ́ẹ̀ tí ó fi OLUWA Alààyè búra pé ẹni tí ó dán irú rẹ̀ wò, kíkú ni yóo kú.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 12

Wo Samuẹli Keji 12:5 ni o tọ