14 Ṣugbọn Amnoni kọ̀, kò gbọ́ ohun tí Tamari sọ fún un. Nígbà tí ó sì jẹ́ pé Amnoni lágbára jù ú lọ, ó fi tipátipá bá a lòpọ̀.
Ka pipe ipin Samuẹli Keji 13
Wo Samuẹli Keji 13:14 ni o tọ