Samuẹli Keji 13:23 BM

23 Lẹ́yìn ọdún meji tí nǹkan yìí ṣẹlẹ̀, Absalomu lọ rẹ́ irun aguntan rẹ̀ ní Baali Hasori, lẹ́bàá ìlú Efuraimu, ó sì pe gbogbo àwọn ọmọ ọba patapata lọkunrin sibẹ.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 13

Wo Samuẹli Keji 13:23 ni o tọ