Samuẹli Keji 13:34 BM

34 Absalomu sá lọ ní àkókò yìí.Kò pẹ́ rárá, lẹ́yìn náà, ọmọ ogun tí ń ṣọ́ ọ̀nà tí ó wọ ìlú rí ogunlọ́gọ̀ eniyan, wọ́n ń bọ̀ láti ọ̀nà Horonaimu, lẹ́bàá òkè.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 13

Wo Samuẹli Keji 13:34 ni o tọ