37 Ṣugbọn Absalomu sá lọ sọ́dọ̀ Talimai, ọmọ Amihudu, ọba Geṣuri, Dafidi sì ń ṣọ̀fọ̀ ọmọ rẹ̀ lojoojumọ.
Ka pipe ipin Samuẹli Keji 13
Wo Samuẹli Keji 13:37 ni o tọ