Samuẹli Keji 13:39 BM

39 Nígbà tí ó yá tí Dafidi gbé ìbànújẹ́ ikú Amnoni ọmọ rẹ̀ kúrò lára, ọkàn Absalomu ọmọ rẹ̀ bẹ̀rẹ̀ sí fà á.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 13

Wo Samuẹli Keji 13:39 ni o tọ