7 Dafidi bá ranṣẹ pe Tamari ninu ààfin, ó ní kí ó lọ sinu ilé Amnoni, kí ó lọ tọ́jú oúnjẹ fún un.
Ka pipe ipin Samuẹli Keji 13
Wo Samuẹli Keji 13:7 ni o tọ